Share this:

ILANA ISE SAA KEJI FUN OLODUN KETA AGBA

 

ISE: EDE YORUBA   KILAASI: SS3

 

Ose Kinni  Atunyewo eko kikun lori Silebu Ede Yoruba

Asa – Elegbejegbe tabi Irosiro

Litireso – Agbeyewo asayan iwe ti ajo WAEC/NECO yan

Ose Keji  Fonoloji Ede Yoruba

Foniimi, Konsonanti, Faweli, ohun Konsonanti Aranmupe, Eda Foniimu kons. Ati ohun.

Asa: Agbeyewo awon Orisa Ile Yoruba: Obatala, Orunmila/Ifa. Itan ni soki nipa Aworo Orisa.

Litireso – Itupale iwe ti ajo WAEC/NECO yan.

Ose Keta  Atunyewo eko lori Oro- Ayalo

Asa – Eto Ebi ati Iserun Eni

Litireso – Kika iwe ti ajo WAEC/NECO yan

Ose Kerin  Ihun Oro – Iseda Oro – Oruko

ecolebooks.com

Asa – Eto Iselu Abinibi ati ti Ode-Oni

Lit: Itupale iwe ti ajo WAEC/NECO yan.

Ose Karun  Atunyewo eko lori Isori Oro: Oruko, Aropo Oruko, Aropo Afarajoruko, Ise abbl.

Asa: Atunyewo eko lori Oge Sise. Aso wiwo, itoju ara, ila kiko abbl.

Lit: atunyewo eko lori alo apamo, apagbe, itandowe abbl.

Ose Kefa  Atunyewo eko lori Isori Oro: Apejuwe, Aponle, Asopo, Atokun

Asa: atunyewo kikun lori Asa Igbeyawo nile Yoruba.

Lit: Itupale iwe ti ajo WAEC/NECO yan.

 

IWE ITOKASI

 • Imo, Ede, Asa Ati Litireso. S.Y Adewoyin
 • Eto Iro ati Girama fun Sekondiri Agba. Folarin Olatubosun.
 • Akojopo Alo Apagbe: Amoo A. (WAEC).
 • Oriki Orile Metadinlogbon: Babalola, A (WAEC).
 • Iremoje Ere Isipa Ode: Ajuwon B. (WAEC).
 • Igbeyin Lalayonta: Ajewole O. (WAEC).
 • Iya Atata: Fadiya, O. (WAEC).
 • Oremi Mi: Aderibigbe, M. (WAEC).
 • Egun Ori Ikunle: Lasunkanmi Tela. (NECO)
 • Omo Ti A Fise Wo: Ojukorola Oluwadamilare. (NECO).
 • Ewi Igbalode: Taiwo Olunlade. (NECO).

OSE KINNI

SILEBU EDE YORUBA

AKOONU

Silebu ni ege oro ti o kere ju ti eemi le gbe jade leekan soso. Apeere:

Ajayi: A-ja-yi =  silebu meta

Olabisi O-la-bi-si  silebu merin.

Adeleke  A-de-le-ke  silebu merin

Olopaa O-lo-pa-a  silebu merin

Gbangbadekun gba-n-gba-de-kun  silebu marun-un.

 

Odo Silebu: ni apa ti o se pataki julo ninu ihun silebu kookan. Iro faweli ati iro

konsonanti aranmupe asesilebu ni o maa n sise gege bi odo silebu. Odo silebu ni o maa n dun ju ninu silebu.

 

Awon iro odo silebu ni a maa n gbo ju ninu oro.

Ori odo silebu ni a maa n fi ami ohun si

Kan-an-n-pa ni odo silebu je ninu ihun silebu.

Ap

wa

gba

sun

 

Apaala silebu -;je iro konsonanti yato si konsonanti aranmupe asesilebu [m,n] ni o maa n sise gege bi apaala silebu.

ap

gbo

dun

ko

we

 

IHUN SILEBU [F1,KF ATI N] NINU ORO OLOPO SILEBU.

Orisiirisii ona ni a le gba se ihunpo silebu ninu oro olopo silebu.

ORO IHUN IYE SILEBU

Aso A/ so  2

f /kf

Bata ba / ta  2  

Kf / kf

Igbale i/gba / le 3

F/ kf /kf

Alupupu   A/lu/pu/pu 4

f/kf/kf/ kf

Konko ko/N/ko 3

 Kf/N/kf  

 

IGBELEWON

1. Kin ni silebu?

b. Salaye ihun silebu pelu apeere.

2. Pin awon oro yii si silebu

Agbalagbaakan

Olowolayemo

Gbangbalakoogbo

Oji ku tu ba-ra orunsaaro

Operekete

 

IGBELEWON

 1. Salaye ni ekunrere lori odo silebu ati apaala silebu pelu apeere.
 2. Eya ihun silebu meloo ni o wa? Fi apeere gbe idahun re lese.
 3. Ki ni pataki konsonanti aranmupe n ati m ninu ege silebu?

   

  IWE AKATILEWA

  Aewoyin S.Y (2009) IMO, EDE, ASA ati LITIRESO YORUBA S.S.3 Copromutt Publishers.

   

  ASA

  ELEGBEJEGBE

  ORIKI

  ORISII

  IPA TI WON N KO NI AWUJO

  AKOONU

  – Elegbejegbe ni egbe ti awon odo, agba ni okunrin tabi ni obinrin ti won je iro da sile ni agbegbe won fun igbega ilu ati ara won.

  Ni aye atijo,iwonba ni ise ti ijoba maa n se fun awon ara ilu.igbega ati idagbasoke ilu tabi igberiko maa n waye pelu iranlowo awon elegbejegbe wonyi, apeere iru egbe bee ni aye atijo ni egbe ogboni.

  Apapo awon agba ilu ti won to omo bii Aadota odun ni won maa n wo egbe ogboni. Ojuse egbe ogboni ni lati fun oba ni imoran.Won ni agbara lati da oba lekun tabi le oba kuro lori ite ti o ba si agbara lo.

   Ni ode-oni,awon elegbejegbe po jantirere. Apeere won ni :-

   Lion’s club

   Rotary club

   Majeeobaje

    Oredegbe ati bee bee lo.

  Ni ilu tabi ileto ti awon egbe wonyii ba wa,orisiirisii ise idagbasoke ni won maa n se bii : – tite tabi titun afara se.

 • kiko ile ero kaakiri ibudoko.

   

  IWULO ELEGBEJEGBE.

 1. Awon egbe ogboni maa n kopa ninu eto iselu awon baba-nla wa.
 2. Won maa n kopa ninu ise bii:- ona yiye,afara odo titun se,aafin oba kiko.
 3. Won maa n kopa ninu pipese owo ajemonu fun awon akekoo ile-iwe giga,pipese eko ofe fun awon akekoo ile-iwe girama,sisan owo idanwo iwe mewaa.
 4. Aaro kikojo,owe bibe,eesu kikojo fun iranlowo egbe ati enikookan omo egbe.

   

  IGBELEWON

 5. Nje egbejegbe ni anfaani Kankan ninu asa Yoruba bi? Se alaye kikun.
 6. Daruko egbejegbe ibile Yoruba marun-un ti o mo.

   

  LITIRESO

  OGBON ITOPINPIN LITIRESO

  Akoonu:

  Eyi ni awon koko to se pataki ti a gbodo mo nipa iwe litireso ti ijoba ya eyi ti a maa ka. Oun akoko ti a gbodo mo ni oruko iwe, Oruko onkowe, ibudo itan, itan ni soki, awon eda itan, ona isowolo-ede, eko ti a ri ko, asa Yoruba ati beebee lo.

  Iwe ti a maa gbe yewo ni OMO TI A TI A FI ISE WO ati ORE MI.

  Oruko Onkowe: oruko awon onkowe iwe naa ni: Ojukorola O. ati Aderibigbe M.

  Ibudo Itan: n’ toka si ilu ti itan inu iwe yii ti waye, awon ilu ti itan naa ti waye ni:

  Itan ni soki:

  Awon Eda Itan:

  Akanlo Ede Ayaworan: owe, akanlo ede, afiwe, awitunwi, asorege, ifohunpeniyan, iforodara abbl.

   

  IWE AKATILEWA

  Simplified Yoruba ati litireso

   

  APAPO IGBELEWON

  1.  a. Kin ni silebu?

  b. Salaye ihun silebu pelu apeere.

  2.  Pin awon oro yii si silebu

  3.  Nje egbejegbe ni anfaani Kankan ninu asa Yoruba bi? Se alaye kikun.

  4.  Daruko egbejegbe ibile Yoruba marun-un ti o mo.

   

  ATUNYEWO EKO

 • Salaye iro konsonanti.
 • Salaye iro faweli

   

  ISE ASETILEWA

 1. ………ni ege oro ti eni lo gba jade leekansoso (a) oro (b) apola (d) silebu
 2. ………..ni a n lo fun idagbasoke ilu. (a) iro (b) egbe (d) aaro.
 3. …………ni maa n gbo ju ninu silebu. (a) odo silebu (b) ihun silebu (d) apaala silebu.
 4. …… ki i se ara erongba elegbejegbe. (a) ona yiye (b) afara tite (d) aibowofagba.
 5. Apeere elegbejegbe laye atijo ni ………. (a) egbe onimototo (b) egbe ogboni (d) Rotary.

   

  THEORY

 6. a. ki ni silebu?

  b. salaye ihun silebu pelu apeere.

  2.  a. kin ni odo ati apaala silebu? Fi idahun re han pelu apeere.

  b. kin ni elegbejegbe?

  d. salaye iwulo elegbejegbe merin ti o mo.

   

   

  OSE KEJI

  FONOLOJI EDE YORUBA

  Foniimu konsonanti

  Foniimu faweli ati ohun

  Eda foniimu konsonanti ati faweli

  Akoonu

  (Iro aseyato)

  Foniimu ni awon iro ti o le fi iyato han laaarin oro kan tabi omiran

  Ap

  Foniimu ni /b/ /d/ /tag/, eyi ti o tumo si pe bi a ba fi iro kan dipo ikeji iyato yoo wa

  Ap

  Ede

  Ere

  Epe

  Ege

  Egbe

   

  Idako foonu faweli – a {a}

  Baba ko ebe – {baba k כ ebe}

   

  Foniimu ede Yoruba pin si ona meta

 • Foniimu konsonanti
 • Foniimu faweli
 • Foniimu ohun
 • Foniimu konsonanti -: iro aseyato ni gbogbo iro konsonanti ede Yoruba fere je ba, pa, wa

  Ap

  /b/ ni eda {b} – to je konsonanti akunyun afeji – ete – pe asenupe.

  O le jeyo nibi gbogbo ap bo /b כ[b כ

  Foniimu Faweli: naa je iro aseyato bi a ba fi faweli kan ropo ikeji iyato yoo wa ninu oro naa.

  Ap.

  Wa

  Wo

  We

  Foniimu faweli pin si ona meji

  Faweli airanmupe

  Faweli aranmupe

  Apejuwe fonimu faweli

  /a/ ni eda [a] – ayanupe, aarin, perese

  o maa n jeyo nibi gbogbo ap s /Sa/ [Sa]

   apa /akpa/ [akpa]

   

  FONIIMU OHUN

  Iro ohun a maa je foniimu tabi toniimu. Eyi nipe ohun ori silebu kan le mu ki oro kan yato si ikeji paapaa ninu ede olohun bii ede Yoruba.

  Foniimu ohun pin si ona meta.

 1. / | / toniimu oke ap Ja
 2. | \ | toniimu isale ap iwa
 3. toniimu aarin

  ap

  wi

  wa

  so

  igba (re re)

  igba (garden egg)

  igba (time)

  igba (calabash)

   

  Eda Foniimu :- ni awon iro ti ko le fi iyato han laarin itumo oro kan ati omiran. Eda foniimu je ifonka alaiseyato ninu ede Yoruba.

  Apeere eda foniimu faweli in

  \ I/ ati / n/

  eyi ni pe bi a ba fi won ropo ara won ninu oro ko ni si iyato.

  Ap.

  ni aya – laya

  ni ana – I anaa

  mo ni aso – mo laso.

  Ogunbambo – Ogunbanbo

  Oronbo – Orombo.

  O kan je eda ikeji bee ni ko si iyato kankan laarin won.

  Eda faweli: eda faweli foniimu faweli ede Yoruba ni / a / an ati כ// on.

  Ap

  Itan  –   Iton

  Iran  –  Iren

  Okan  –  Okon

   

  IGBELEWON

 • ki ni foniimu? Salaye ni ekunrere.
 • Ki ni eda foniimu? Salaye ni ekunrere.
 • Fun fonoloji ni oriki.

   

  IWE AKATILEWA

  Aewoyin S.Y (2009) IMO, EDE, ASA ati LITIRESO YORUBA S.S.3 Copromutt Publishers.

   

  {BZTQLQ/)R*XZ]NLQ

  Itan so nipa Obatala wi pe oun ni ipo re ga julo ninu gbogbo orisa. Oun ni o lagbara julo ninu won, oun si ni asaaju won patapata. Oruko meji ni a le pe orisa yii nile Yoruba. A le pe e ni Obatala, eyi ti o ja si ‘Oba ti ala’, a tun le pe e ni Orisa-nla eyi ti o ja si ‘Oba ti-o-nla’, Oba ti o tobi.

   

  Oun kan naa ni a gbo pe o je igba keji eledaa Olodumare. O di igba keji nitori pe oun gan-na ni Eledaa koko da. Leyin eyi ni Eledaa fun un ni agbara lati ran oun lowo ninu ise re gege bi Eledaa. A gbo pe Obatala ni i se oju, imu, enu, eti ati awon eya ara yooku leyin ti Eledaa ba ti da ara borogidi tan.

   

  Awon aro, amunkun, afin, abuke, afoju ati awon miiran bee la n pe ni ‘eni orisa’.

  Awon wonyi ni Obatala fi ise tabi owo agbara re han. A sit un n pe e ni ‘Alamo Rere’ nitori pe o ni anfaani lati lo amo re fun siseda eniyan. Igbagbo awon oloosa Obatala nip e bi Olodumare ba se ara tan, yoo fi ara naa ranse si Obatala ki o tan eda naa wa si aye, ti yoo si maa so titi ojo aye re.

   

  Obatala ko fe epo, osun bi ko se ala. Aso funfun ni awon aworo Obatala ati awon olusin re maa n lo ni ojo odun re. Iyan ati obe funfun ni ti Obatala, inu igba funfun ni a o de iyan re si. Obe ti a fi eran igbin ati ori se ni ti Obatala. Aso funfun gele funfun ileke fun ni iyawo Obatala sa maa n lo ni ojo odun re.

   

  IGBELEWON

  Salaye orisa Orunmila.

   

  IWE ITOKASI

  Olu, D. ati Jeje, A. (1970) AWON ASA ATI ORISA ILE YORUBA Onibonoje Press.

   

  IFA

  Nigba ti a ba daruko Ifa, okan opolopo eniyan ni o maa n lo si odo Orunmila. Looto ni Orunmila je baba Ifa sugbon kii se oun nikan ni Ifa ti a n d anile Yoruba.

   

  Ni aye atijo ko si ohunkohun ti a le se nile Yoruba lailo beere lodo Ifa. Ti a ba fe fe iyawo, a o lo beere boya wundia ti okan wa so ni yoo je iyawo rere abi bee ko. Bi a ba bimo a nila ti lo beere esentaye omo lodo Ifa abbl. Awon ohun ti a n se nile Yoruba ti a kii fi ti Ifa si ko wopo. Owo Ifa ni a ti n beere eni ti o maa j’Oba ohun ni o mo eni ti yoo yooku ni aarin ilu. Paripari re ni wi pe owo Ifa ni a ti beere ojo ti o ba to ti o si ye lati bo Ifa ni odun. Eleyi fi han kedere lori ipo ti awon Yoruba fi ifa si.

   

  Yato si orunmila, awon Ifa miiran ti o wa ni ile Yoruba ni Agbigba, obi, Ile, olokun, Olokun-awo, wo-mi-pee.

   

  Awon onitan so fun wa pe Orunmila ni eni naa ti o Olodumare ran lati wa se igba keji re ni aye. Odo re ni a o ti maa beere orisii nnkan nitori o je eni ti o gbon lopolopo. Awon tile so pe o wa nibe nigba ti Olodumare da gbogbo ohun ti o n be ninu aye pelu eniyan paapaa idi re e ti a fi n pe e ni Eleri-ipin. Apeja oruko Orunmila ni ‘Orun-mo-eni-ti-o-maa-la’

   

  Itan kan so w ape o ni baba ati iya sugbon won ko gbe ile aye pelu re. )rok9 ni or5k[ bzbq Zlqj3ru ni or5k[ 8yq r2 ni 0de =run. +sany8n j1 oluran lowo pztzk8 f5n +r5nm8lz.

   

  Ekuro ni Ifa ti o j1 irinsc f5n +r5nm8lz. Ifa je irinse fun +r5nm8lz. Awon babalawo ni o je aworo Orunmila tabi Ifa.

   

  IGBELEWON

  Salaye iyato ti o wa laarin orunmila ati Ifa.

   

  IWE ITOKASI

  Olu, D. ati Jeje, A. (1970) AWON ASA ATI ORISA ILE YORUBA Onibonoje Press.

   

  LITIRESO

  Kika iwe ti ijoba yan

   

  IGBELEWON

 1. a. Kin ni foniimu

  b. Ona meloo ni foniimu pin sii

  2.  Se agekuru ohun ti e ka ninu iwe adakedajo.

   

  IWE AKATILEWA

  Imo Ede Asa ati Litreso Yoruba SS3. S.Y Ademoyin o.i 83 – 90

   

  APAPO IGBELEWON

 2. Salaye orisa Orunmila.
 3. ki ni foniimu? Salaye ni ekunrere.
 4. Ki ni eda foniimu? Salaye ni ekunrere.
 5. Fun fonoloji ni oriki.

   

  ATUNYEWO EKO

  Ko iyato merin laarin iro konsonanti ati iro faweli sile.

   

  ISE ASETILEWA

  1. Foniimu ni _______ (a) iro ti a pe (b) to le fi iyato han (d) iro ti o dun

  2. Faweli pin si ona ____ (a) meji (b) meta (d) merin

  3. Iro ______ naa ni a mo si toniimu (a) faweli (b) konsonanti (d) ohun

  4. eda foniimu konsonanti ni _______ (a) / b/ ati / d/ (b) /i/ ati m (d) /I/ ati / n/

  5. Idako ‘on’ ni _____ (a) / on / (b) /category/ (d) / כ

   

  APA KEJI

 6. Pelu apeere salaye iyato to wa laarin iro foniimu ati eda foniimu .
 7. Se adako – foonu fun awon faweli ti a fala si nidi ninu awon oro wonyi: Imu, Won, Yen,

  Esin, Aso, Eyele, ati Sola lo si ile ijosin.

 8. Salaye iyato ti o wa laarin Obatala ati Orunmila.

   

   

  OSE KETA

  ORO – AYALO.

  Inu ede ti a ti n ya oro lo.

  Ona ti a n gba ya oro wonu ede Yoruba.

   

  Akoonu

  Oro – ayalo -: ni awon oro ajeji ti a maa n ya wonu ede Yoruba lati inu ede miiran

  Oro – ayalo -: ni mimu oro lati inu ede kan wo inu ede miiran lona ti pipe ati kiko re yoo fi wa ni ibamu pelu ede ti a mu-un wo.

  Oro – ayalo maa n mu ki ede dagba.

  Bakan naa, o maa n je ki oruko wa fun awon nnkan ati ero tuntun ti o ba n sese n wo awujo wa

   

  Yoruba ni ilana meji ti won n gba ya oro wo inu ede Yoruba, awon naa ni

  – Ilana afetiya

  – ilana afojuya

  Ilana afetiya -: eyi ni pipe oro ayalo ni ona to sunmo bi awon elede se n pe oro gan-an

  Bible – Baibu

  Peter  –  Pita

  Table  –  Tebu

  Esther –    Esita

  Deacon –  Dikin

  Council –  kansu

  Al- basal –  alubosa

   
   

  Ilana afojuya :- eyi ni kiko oro ni liana eyi to sunmo bi awon elede se n ko.awon elede se n saaba maa n lo ilana yii

   
   

  Soldier –  soja

  Table –  tabili

  Peter –  peteru

  Esther –  esiteri

  Bible –  Bibeli

  Deacon –  Diakoni

  Paradise  –  paradise

  Hebrew  –  Heberu  

   

  Inu awon ede wonyii ni a ti n ya oro wo inu ede Yoruba

  Ede Geesi

  Ede Larubawa

  Ede Faranse

   

  Bi oro ayalo se wonu ede Yoruba

  Eyi ni orisirisii ona ti oro ayalo gba wonu ede Yoruba

 9. Esin:- nipase esin musulumi ati esin Kristi ti won mu wa fun wa ni a se ni awon oro wonyi: mosalasi, soosi, alijanna, angeli bibeli, pasito, kurani abbl
 10. Ajose owo:- eyi ni ajose owo laarin Yoruba ati awon eya miiran ap: senji, korensi, wisiki, buluu
 11. Eto iselu:- Nipase ijoba ajeji ti awon larubawa ati Geesi mu wa ni a ti ya opolopo oro bii seria, kootu, sinato
 12. Asa ati olaju:- ajumose nipa asa ati olaju mu ki a ya opolopo oro lo ap: yigi, marede
 13. Eto eko:- eyi ni oro ti a ya nipa eto eko ap tisa, boodu,

   
   

  AWON IRO TI A FI N SE AARO ARA WON

  Ki oro ede Geesi ti a ya lo to le di ara oro mu ede Yoruba, o gbodo tele ofin ede Yoruba

 14. Konsonanti ki i gbeyin oro ninu ede Yoruba bi oro ayalo ba ni, a o fi faweli ti o ye seyin re, o le je: i, u  a tabi o, ap

  Bread – buredi

  Gum – goomu

  Bed – beedi

  Shirt – seeti

  fail – feeli

  Glass – gilaasi

  Gold – goolu

   

  ii.  Yiyo konsonanti ipari oro ayalo kuro ap

  Mobil – mobi

  Moses – mose

  Jesus – jesu

  Lazarus – lasaru

   

  iii.  Yiya isupo konsonanti oro- ayalo fifi faweli ya isupo konsonanti ap

  bread – buredi

  milk – miliiki

  iray – Tiree

  station – Tesan

  belt – beliiti

   

  iv.  Ifiropo konsonanti ninu oro ayalo Nigba miirran konsonanti oro Geesi maa n yato si ti Yoruba ap:

  Lazarus – lasaru

  Church – soosi

  Queen – kun-yin

  Valve – faafu

  Stamp – sitanbu

  Cup – koobu

   
   

 • Ami gbodo wa lori oro- ayalo
 • Oro ayalo lo maa n bere pelu ami ohun oke
 • Faweli aranmupe maa n bere oro ayalo
 • Iwulo oro ayalo
 • Oro ayalo lo maa n mu ki edi dagba
 • Nipa yiya oro lo a maa n ri oruko fun awon nnkan ati ero tuntun ti o ba sese n wo awujo wa.

  Ofin ti o de oro ayalo

   

  IGBELEWON

  1. Kin ni oro-ayalo?

  Ona meloo ni a n gba lati ya oro lo? Salaye won pelu apeere

   

  IWE AKATILEWA

  Aewoyin S.Y (2009) IMO, EDE, ASA ati LITIRESO YORUBA S.S.3 Copromutt Publishers.

   

  ASA

  AWON ISERUN ENI

  Akoonu

  Awon iserun eni tumo si baba-nla eni, ti o se iran eni sile tabi ori eni ti iran kan ti bere. Ko si iran kan ni ile Yoruba ti ko ni awon ti o see nitori pe ‘okun ki i gun titi ki o ma ni ibi ti o ti fa wa.

  Awon baba-nla wa ti a n toka si yii ti wa nigba iwase, won ti se gudugudu meje ohun yaaya mefa nigba aye won.

  Awon Yoruba gbagbo pe odo ki san ki o gbagbe orisun re, opolopo igba ni won maa n pe oruko baba-nla fun iyonu ati aabo nitori pe won gbagbo pe eni to ba ti ku ni agbara nla lati bukun awon ti won je iran won ni aye.

  Akoko odun tabi loorekoore ni a maa n se etutu lati tu awon iserun eni loju fun oore ti won n reti lodo won.

  Odoodun ni awon iran miiran maa n bo iserun won tabi nigba ti wahala tabi idarudapo ba wa ninu ebi won.

   

  Ebi kookan ni o ni ojubo ti won ti n bo iserun won, o le je agboole tabi ni eyin odi ilu. Iru eyin odi yii le je ibi ti baba-nla won tedo si nigba iwase.

   

  Ogangan ibi ti oku ba kori si ni won ti n se etutu

  Orisiirisii ohun jije mimu ni won n bo iserun eni, agbo tabi agutan adie abbl. Won yoo si ro eje re si oju oori iserun won naa, won yoo da obi, ti o ba si ti yan, o ti gba niyen, akoko ayeye ni o maa n je fun gbogbo ebi

   

  Ni ile Ijebu Agemo ni won nse. Awon ni ipinle Eko kii fi Adamu – Orisa sere.

  Ila oju, oriki –orile ati isesi iran kookan je eyi ti a fi n da ara wa mo, ti o si n mu iserun eni wa si iranti.

   

  Inu oriki-orile ise, ise, iwa, esin, ati eewo iran ni a ti n gbo oniruuru oruko ti an baba-nla wa ti je seyin.

  Ap

   

  Iran onikoyi je iran jagun, eyi si han ninu oriki ati itan iran won, baba –nla won je jagunjagun.

  Iwa akin hihu ko si fi iran yii sile. Iran aagberi ko fe gbagbe oogun abenu gongo.

  Iran Olofa kan o je gbagbe ijakadi.

   

  IGBELEWON

 1. Ki ni iserun eni tumo si?
 2. Daruko awon iserun ile Yoruba ti o mo.

   

  IWE AKATILEWA

  Aewoyin S.Y (2009) IMO, EDE, ASA ati LITIRESO YORUBA S.S.3 Copromutt Publishers.

   

  ETO EBI

  Ni ile Yoruba, ebi ni a tun n pe ni alajobi tabi molebi. Alajobi ni iya, baba, egbon, aburo ati ibatan eni ni apapo. Eto ebi ni opomulero ti o gbe asa, ise, ati ibara-eni-gbepo awon Yoruba duro. omo nibi-niran ni awon Yoruba. Bi won se tan si ile baba ni won tan si ile iya.

   

  Eto ebi bere lati inu ile. Gege bi asa baba ni olori ile, iya ni atele ki o kan awon omo gege bi ojo ori won. Iko kokan ni o ni ipa ti o n ko lati mu ki ife, isokan, laafia ati ajosepo wa ninu ebi.

   

  Lara awon ibasepo ti o wa ninu ebi ni:

  Ise obi si omo

  Ise omo si obi.

  Ibasepo laarin omo iya si omo iya

  Ibasepo laarin Obakan si Obakan

  Ibasepo laarin idile eni ati baba eni

  Ipo Baale ati ojuse re

  Ipo Iyaale Ile ati ise re

  Ipo Obinrin ile

  Ipo Orogun

  Ipo Omo Osu ati ise won

  Ipo Omokunrin Ile ati ise won

  Ipo Omobinrin ile

  Awon Alejo tabi Alabagbe

   

  IGBELEWON

 3. Salaye awon wonyi: Obakan, Iyekan-eni, Omo Osu, Obinrin Ile ati Omobinrin Ile.
 4. Ki ni ojuse Baale Ile? Salaye ni kikun.

   

  IWE AKATILEWA

  Aewoyin S.Y (2009) IMO, EDE, ASA ati LITIRESO YORUBA S.S.3 Copromutt Publishers.

   

  LITIRESO

  Kika iwe ti ajo WAEC yan

  IGBELEWON

  1.  a. Kin ni iserun eni?

  b. Igba wo ni a n bo iserun eni?

  d. Kin ni a fi n bo won?

   

  IWE AKATILEWA

  Imo Ede Asa ati Litireso Yoruba (SS3) S.Y Adewoyin 277 – 279

   

  APAPO IGBELEWON

 5. Kin ni oro-ayalo?
 6. Ona meloo ni a n gba lati ya oro lo? Salaye won pelu apeere
 7. Salaye awon wonyi: Obakan, Iyekan-eni, Omo Osu, Obinrin Ile ati Omobinrin Ile.
 8. Ki ni ojuse Baale Ile? Salaye ni kikun.

   

  ATUNYEWO EKO

 9. Ki ni oro oruko?
 10. Ki ni oro aropo oruko?
 11. Ko iyato merin laarin oro oruko ati oro aropo oruko.

   

  ISE ASETILEWA

 12. Awon Iserun eni tumo si (a) Baba-nla eni (b) eni ti o se iran eni sile (d) eni to na omokunrin ile
 13. Inu _______ ni a ti n gbo nipa oniruuru oruko idile (a) oriki orile (b) iwure (d) ofo
 14. Ojubo iserun eni le wa ni _____ ati (a) Inui le (b)agboole (d) ilu odikeji
 15. Ona _____________ ni a le gba ya oro lo ninu ed Yoruba (a) meji (b) meta (d) merin
 16. A ya pasito ni pase _____(a) esin (b) eto eko (d) imo ero

   

  APA KEJI

 17. Kin ni oro – ayalo?

  b. Ona meloo ni a n gba ya oro wonu ede Yoruba

  d. Ko irisi awon oro Geesi wonyi sile leyin igba ti a ba ti ya won wonu ede Yoruba

  Teacher, Starch, Milk, bread, class, scale, block, trouser, brother, shilling

 18. Kin ni iserun eni

  b. Daruko apeere Iserun eni meta nile Yoruba

  d. Daruko igba ati ohun ti a si n bo iserun eni.

  3. Salaye eto ebi ni kikun.

   

   

  OSE KERIN

  ISEDA ORO-ORUKO

  IHUN ORO (ISODORUKO)

  IGBESE

  Bi a se n seda oro oruko nipa lilo afomo ibere

  AKOONU:-

  Iseda oro-oruko je siseda oro-oruko lati ara oro-oruko tabi oro-ise nipa afomo lilo. Bi a ba fe seda oro oruko eyi ni awon igbese ti a ni lati tele.

  1.  Nipa lilo afomo ibere

   Nipa lilo afomo aarin

   Nipa sise apetunpe kikun

   Nipa sise apetunpe elebe

   Nipa sise akanpo oro-oruko

   Nipa sise isunki odidi gbolohun

  i.  Lilo afomo ibere

  A le lo afomo ibere pelu oro-ise tabi lati seda oro-oruko. Iru oro-oruko bayii gbodo ni ajose pelu oro ise ti a lo pelu afomo. Awon afomo ibere naa ni a, e, e, i o o u, alai, ai, o ni, oni abbl.

   

  Apeere

  a  +  yo  =  ayo

  a  +  lo  =  alo

  a  +  to  =  ato

  o  +  ku  =  oku

  o  +  bi  =  obi

  i  +  to  =  ito

  i  +  fe  =  ife

  e  +  gbe  =  egbe

  e  +  to  =  eto

  e  +  te  =  ete

  e  +  ko  =  eko

  o  +  le  =  ole

  o  +  mu  =  omu

  i  +  rin  =  irin

  ai  +  sun  =  aisun

  ai  +  ni  =  aini

  ati  +  lo  =  atilo

  ati  +  je  =  atije

  on  +  te  =  onte

  alai  +  gbon  =  alaigbon

  alai  +  mo  =  alaimo

  oni  +  igi  =  onigi

  oni  +  omo  =  olomo

   

  ii.  A le lo afomo ibere pelu apola-ise eyi ni pe oro-ise ati oro-oruko

  Apeere

   a  +  ko  +  orin  =  akorin

   a  +  ko  +  ope  =  akope

   a  +  da  +  ejo  =  adajo

   o  +  da  +  oran  =  odaran

   ati  +  de  +  ade  =  atidade

   o  +  se  +  ere  =  osere

   o  +  da  +  oju  =  odaju

   

  IGBELEWON

  Kin ni iseda oro-oruko?

  Daruko ona ti a n gba seda oro- oruko

   

  IWE AKATILEWA

  Aewoyin S.Y (2009) IMO, EDE, ASA ati LITIRESO YORUBA J. S.S.3 Copromutt Publishers.

   

  Asa

  ETO ISELU ABINIBI ATI ODE ONI

  Ipa ti baale ile, Iyaale-ile omobinrin ile, omokunrin ile, omo osu n ko ninu eto  isakoso agbo ile ati ebi gbigboona.

   

  Eto iselu ni ile Yoruba bere lati inu ile, gege bi asa ,baba ni Olori ile, iya ni atele bee ni awon omo naa ni ojuse bi ojo ori won ba se telera.

  Eto agbo-ile ni ipile eto ijoba ni ile Yoruba. Olori agbo-ile ni

   

  Baale: ni eni ti o ba dagba ju lo ni o n je oye yii. Kii se oye ti a maa n du, ti bale kan ba ku ni eni ti o ba tun dagba ju miran yoo je.

   

  Baale ni alase ati alakooso agbo ile, Ohun ti o ba so ni abe ge. Ko si eni ti o gbodo fi owo pa ida re loju.

   

  Ile maa n to beere ninu agbo ile nla ni won a wa mo ogiri yii gbogbo ile bee ka, ilekun kan yoo wa ni enu ona abawole tabi abajade kuro ninu agbo ile.

   

  Baale kii gbe eyin odi, aarin agbo – ile ni o maa n gbe lati mojuto gbogbo ohun ti o ba n lo.

  Igbejo maa n wa ti won maa n jokoo si lati gbo ejo pelu awon agbaagba bii merin. Omo kekere kan yoo maa fe abebe si baba ni ara.

   

  ISE Baale

  Ija pipari ni agbo-ile: ti ede aiyede ba waye ise baale ni lati yanju re. Totun tosi yoo ro ejo, ki in to da ejo, bale lo maa kadii ninu ohun to ba si so ni abe ge.

  Fifi omo foko: bi omobinrin ile bafe loko, odede bale ni won yoo ti wule fun-un. Bi iyawo tuntun ba si wole o gbodo de odede baale fun adura.

   

  Imojuto omo ile lokunrin ati lobinrin o gbodo mo Ijade at iwole awon odo agbo ile.

  Ogun pipin: Odede baale ni won ti n saato bi won yoo se pin ogun fun awon omo oku ni idi igi kookan.

  Iyaale: ni Obinrin ti o dagba ju ni iye odun ti won wo ile oko. Oun ni igbakeji bale ninu eto iselu agbo ile.

   

  O je asoju ati alamojuto awon iyawo ile ati omobinrin ile.

  Ise re ni lati mo igba ati akoko ti a bi omo lati yanju aawo ti o waye nipa ojo ori.

  Oun ni yoo toju iyawo asesegbe oyun inu, omo ikoko ati eto ila kiko fun omo tuntun.

  Iyaale gbodo ni imo kikun nipa ita idile, oriki ile oko, ti yoo si maa ko awon atele re gbogbo.

   

  Omokunrin Ile: ni awon gende okunrin ti won ti laya tabi ki won je odo.

  Awon ni bale maa n ran ni ise bi ile oku gbigbe, oko ile riro, ona yiye, oju ogun lilo sisin ibi omo si baluwe abbl awon ni won n pa eran nibi inawo apa eran ni won maa n fun won. Won maa n wa nibi ti bale ti n pari ija.

   

  Obinrin ile,! Awon ni iyawo agbo-ile, ojuse won ni lati rogba yi iyaale ka, ki won sa pa ofin re mo.

   

  Awon ni won maa n dana ounje ni akoko odun tabi ayeye. Awon ni won maa n sun rara nibi inawo idile oko won.

   

  Awon lo maa n se itoju iyawo titun ati iyawo ile to ba bimo. Awon lo maa n jora fun iya omoawon lo maa n gba eyin eran.

   

  Omo osu Ile -: ni awon agba obinrin ti won ti losi ile oko, ti won wa pada wa maa gbe ni ile baba won.

  Won maa n ni enu ninu oro ebi, awon lo maa n gba aya eran ti won ba pa.

   

  Omobinrin ile-: ni awon omobinrin ti ko tii lo si ile oko. Won maa n kopa ninu oro ile

   

  Ojuse won ni lati lo ki iyaawo ile to ba bimo.

   

  IGBELEWON

 19. Salaye lori Bqql3, Bqql2, *j0y4 zti {ba
 20. Salaye lori Ijoba Ibile Ijoba Ipinle ati Ijoba Apapo.

   

  ETO ISELU ODE-ONI

  Ni aye ode-oni eto iselu ti yato patapata is ti aye atijo.

  Ni aye ode-oni, eto iselu ti aye ode-oni ni a n lo gomina ni Olori ati alase ni ilu kookan ti o si ni awon komisanna ti won jo n tuko eto ilu. Loooto ni awon oba si wa sugbon won ko ni agbara bii ti aye atijo mo

   

  Bee naa ni a ni awon alaga fun ijoba ibile ati awon Kanselo fun agbegbe ti won n ri si idagbasoke ilosiwaju agbegbe won nigbat ti olori orile –ede je olori patapata fun orile-ede, ti ohunkohun ba sele ni ipinle Olori-onle-ede ni won yoo ti to leti, ti o ba si je ni agbegbe tabi adugbo ni kaunselo a fi to alaga leti, ti apa alaga ba kaa yoo see sugbon ti o ba ju agbara re lo, o fi to gomina leti ise naa yoo si di sise.

   

  Ti o ba ju agbara gomina lo, oun naa a fi to Olori Orile-ede leti

  Ajosepo to dan moran si wa laarin ijoba ode-oni pelu awon oba nitori pe gbogbo won jo n sise po fun idagbasoke, alaafia ati ilosiwaju ilu ni.

  Bee naa ni a ni Orisiirisii awon alamojuto to n ri si or nipa awon obinrin, odo eto nipa oro aje, ayika, eto irinna, ina monmona abbl. Omi ero.

  Eto abinibi is n tesiwaju ni awon igberiko wa sugbon ko fi bee fese rinle mo bii ti aye atijo.

  Fun tie to idajo-ni aye ode oni a ni ile ejo ni ti adajo yoo ti dajo bee ni awon soja, Olopaa, Omo ogun oju omi ati ti ofurufu fun idaabobo ilu in aye ode-oni.

   

  IGBELEWON

 21. Salaye lori Bqql3, Bqql2, *j0y4 zti {ba
 22. Salaye lori Ijoba Ibile Ijoba Ipinle ati Ijoba Apapo.

   

  APAPO IGBELEWO


 23. Seda oro oruko 10 nipa: afomo ibere.
 24. Seda oro oruko 10 nipa afomo aarin
 25. Seda oro oruko 10 nipa apetunpe.

   

  ATUNYEWO EKO

 26. Fun awon oro oruko yii ni apeere mejimeji: afoyemo, ibikan, asonka, alaisonka. Aridimu.
 27. ko apeere oro aropo oruko: eni kin-in-ni eyo oluwa. Enikeji opo oluwa, eniketa eyo opo.

   

  IWE AKATILEWA

  Aewoyin S.Y (2009) IMO, EDE, ASA ati LITIRESO YORUBA S.S.3 Copromutt Publishers.

   

  ISE AMURELE

  1.  Aseda ife nipa lolo ____________________________

   (a)  afomo aarin  (b)  afomo ibere  (d)  apetunpe

  2.  Afomo ibere ninu alaigbon ni ________________

   (a)  ala (b)  alai (d)  gbon

  3.  Nje awon Yoruba gbagbo ninu iye leyin iku

   (a)  rara (b)  won gbagbo  

  4.  Awon ___________________________ni won maa n ku pelu Oba laye atijo ki o ba le ri won ran nise ni ile ibomiran ti o ba ja si.

   (a)  Abobaku  (b)  eru (d)  ara ile oba

  5.  ___________________ni a n pe eni ti o ti ku, ti o tun lo si ile ibomiran

   (a)  ayorunbo  (b)  Akudaaya  (d)  eni irapada

  APA KEJI

  1.  Awon ona wo ni a le gba seda oro-oruko ninu ede Yoruba?

  b.  Lo afomo ibere lati seda oro-oruko marun-un

  2.  Nje awon Yoruba gbagbo ninu iye leyin iku

   

   

  OSE KARUN-UN

  +R+ AR_P)OR%K{.

   

  +R+ AR_P)OR%K{.

 • Or7k8
 • Zb6dq +r= Ar-p0 Or5k[
 • Ztc =r= Ar-p0 Or5k[
 • *r7s7 =r= Ar-p0 Or5k[.

   

  AKOONU

  +r= ar-p0 or5k[ ni a mqq n l0 d7p0 =r= or5k[ n7n5 zp9lz or5k[. Zpccrc:

 1. B.
 2. ‘B9l5 jc zkzrz’    =  ( jc zkzrz.’
 3. ‘ew5r1 jc zgbzdo B9lq’  =  Ew5r1 jc zgbzdo r2.

   

   

  T7 a bq wo gb9l9h6n zk-k-, a r7 ‘B9l5 zti zkzrz’ g1g1 bi =r= or5k[ s6gb9n n7gbz t7 9 di 8gbz t7 a f1 t5n gb9l9h6n yii s[. A lo zw[n =r= m87rzn d7p0 zwon =r= or5k[ y87 ‘O zti r2’ zwon =r= or5k[ t7 a l0 d7p0 =r= or5k[ m3j34j7 y87 ni z n p4 n7 =r= ar-p0 or5k[. $y7 ni 9 scl2 s7 gb9l9h6n kej8 nqz. ‘ew5rc, zgbzdo zti B-lq jc =r= or5k[ n7n5 gb9l9h6n y87 s6gb.n n7gbz t7 a f1 t5n ‘B-lq’ s[ ni apq kej8. A lo =r= m78rzn d7p0 ‘r2’ =r= y87 ni z n p4 ni =r= ar-p0 or5k[. Or7s87r7s87 =r= ar-p0 or5k[ ni 9 wz. D72 n7n5 w[n ni: mo, r2, wa, c, o, 9, w-n, a abbl.

   

  Zb6dq +r= Ar-p0 Or5k[.

  +r= ar-p0 or5k[ n7 4t0 t9 n t-ka s7 iye bi: cy[ tzb7 =p=. Cy[ d5r9 f5n cy[ kan. Zw[n =r= ar-p0 or5k[ t7 9 le sis1 f5n cy[ kan soso n7gbz ti =p= d5r9 f5n 4y7 t7 9 p= ju =kan l[. B7 m3j8, m1ta, m1rin…… Zpccrc

  ( l[ cy[ ni 9 ].

  W-n wa   =p= ni w-n].

   

  +r= ar-p0 or5k[ ni 4t0 t9 n t-ka s7 cni. Zpccrc.

  Cnikinni /4y7 ni cni t7 9 n s=r=.

  Cnikej8 / 4y7 ni cni t7 z n s=r= sii. Tzb7 cni t7 z n bq s=r=.

  Cnikcta / 4y7 ni cni tzb7 ohun t7 z n s=r= r2.

   Mo k[ l1tz.

   ( k[l1tz

   ( k[ l1tz.

   

  3. +r= ar-p0 or5k[ ni 4t0 ipin si ipo.

    IYE  Cy[  +p=

  Cni k8n7nn7 mo  a

  Cnikej8 O  c

  Cnikcta Ó  w-n.

   

  4. A ko le fi =r=zsop= so =r= ar-p0 or5k[ m3j8 pap=. Zpccrc:

  mo zti o

  wa zti w[n.

   

  5. A k0 l4 lo =r= ar-p0 or5k[ p2l5 da zti nk-, ni, ko. Zpccrc:

  mo n ko?

  E da?

  O ko?

   

  6. A k0 l4 lo 2yqn p2l5 =r= ar-p0 or5k[ Zpccrc:

   mo nqz

   e ganan.

   

   

  *R&S& +R+ AR_P)OR%K{.

   +nz m1ta pztzk8 ni a l4 gbz lo =r= ar-p0 or5k[ n7n5 gb9l9h6n. i. ( le sis1 ol6wz ii. Zb=. iii. @yqn n7n5 gb9l9h6n.

   

 4. Ipo Ol6wz;
  . =r= ar-p0 or5k[ mqq n sis1 ol6wz n7n5 gb9l9h6n,

   

  IYE  CY{ +P+.

  Cni k8n7nn7 mo a

  Cnikej8 o c

  Cnikcta 9 w-n.

   

  Zpccrc:

  Mo n j9.  A n j9.

  O n j9. E n j9.

  Ó n j9 W-n n j9.

   

 5. Ipo Abo : =r= ar-p0 or5k[ mqq n sis1 zb= bakan nqz n7n5 gb9l9h6n.

   

  Iye Cy[ +p=.

  Cni k8n7nn7 mi wa

  Cnikej8 o y7n

  Cnikcta zfzg6n  w[n

  faweli

   

  Zpccrc: Baba na mi.

  Bolu n pe o/e.

  Oluko pe e.

  Oba ri wa.

   

 6. Ip0 #yqn : =r= ar-p0 or5k[ mqq n wz n7 ip0 2yqn n7n5 gb9l9h6n.

   

  IYE  EYO OPO.

  Cni k8n7nn7 mi wa

  Cnikej8 rc/c yin

  Cnikcta rè/è w[n.

   

  Zpccrc:

  Ajq mi pa eku

  Aja re pa eku

  Aja r2 pa eku.

  Ile wa ni a ti v-

  Ax[ yin ni w-n n w0.

  Ajq w[n ki i jc 8v2.

   

  IGBELEWON:

  K[ zw[n =r= ar-p0 or5k[ w=ny7 s7l2 k7 o s8 lo =k==kan w[n n7 gb9l9h6n.

 7. +r= ar-p0 or5k[ cy[ enikinin ni ip0 ol6wz
 8. +r= ar-p0 or5k[ =p= enikeji ni ip0 zb=.
 9. +r= ar-p0 or5k[ cy[ eniketa ni ip0 ol6wz
 10. +r= ar-p0 or5k[ =p= eniketa ni ip0 zb=.

   

  IWE AKAILEWA

  Ad3w[yin S.Y (2006) *m=, $d4, Zxz zti L7t7r3s= Il3 @k- S1k-nd7r8 Zgbz. Copromutt Publishers oj5 8w3 142.145.

   

  +R+ AR_P) ZFARAJOR%K{.

 • Or7k8
 • Abuda =r= ar-p0 zfarajor5k-
 • *r7s7 =r= ar-p0 zfarajor5k[.

   

  ZK((N% :

  +r= Zr-p0. Zfarajor5k[ ni 8ses7 t9 faraj[ ti =r=or5k[ s6gb-n 9 m5 4t0 iye zti cni lqra zb6dq =r= ar-p0 or5k[. Zw[n =r= ar-po zfarajor5k[ ni w=nyii; 4mi, 8w[, 0un, zwa, 2yin, zw[n. F5n zpccrc:

  $mi k0 r7 B-lq.

  Il3 zwa d6n.

   

  Zb6dq +r= Ar-p0 Zfarajor5k[.

  +r= ar-p0 zfarajor5k[ ni 4t0 8ye zti cni.

  Ate =r= ar-p0 zfarajor5k[.

   

  IYE CY{ +P+.

  Cni k8n7nn7 4mi zwa

  Cnikej8 8w[ 2yin

  Cnikcta 0un zw[n.

  Zpccrc : 8w[ ni w[n ran.

  Zwa nqz n b=.

   

  ii. A l4 lo =r= zsop= lqti so =r= ar-po zfarajor5k[ m3j8 pap=. Zpccrc.

   4mi zti 8w[.

   Zwa zti 2yin.

  iii. +r= ar-po zfarajor5k[ le jcy[ p2l5 zw[n w5nr2n bii dz, nk-, ko. F5nZpccrc.

  8w[ n k-?

  )un dz?

  @yin n k-?

 1. S7l3b6 m3j8 ni =r= ar-po zfarajor5k[ mqq n ni. F5nZpccrc..

  4mi – 4 /mi.

  8w[ – 8 /w[.

 2. +r= ar-po zfarajor5k[ le gba 2yqn. F5nZpccrc.

  4mi nqz wa.

  Zw[n ganan wq.

  A l4 gb3 =r= ar-po zfarajor5k[ sqqj5 w5nr2n zk7y4s7 alqtcnum. ‘ni’ F5nZpccrc.

  @yin ni =gq n p4.

  $mi ni mo ra 8w3 nqz.

   

  *R&S& +R+ AR_P) ZFARAJOR%K{.

  Ix1 ol6wz ni =r= ar-po zfarajor5k[ mqq n se n7n5 gb9l9h6n. F5nZpccrc.

  $mi nqz mu [szn.

  )un ni w-n n bqw7.

   

  *GB#L#W+N

  K[ zpccrc. Zw[n =r= w[nyi s7l2:

 3. Enikin-in-ni =p=
 4. Cni kcta cy[
 5. Cni kej8 cy[
 6. Cnikej8 =p=.
 7. Cnikcta =p=.

  IWE AKZTILEWA

  Adewoyin S.Y (2006) Imo, 4d4, Zxz zti Litireso Yor6bq Oju iwe 147.151 Ile Eko Sekondiri Agba. Copromutt Publishers.

  +R+ ZP_NL#.

  ZK((N^

  +r=Zp-nl3 j1 =r= t7 9 mqq n fi k5n 8tum= =r= =r=8se n7n5 gb9l9h6n, 9 mqq n se zfik5n 8tum= f5n zp9lz8se, ti y90 s8 j1 k7 8tum= r2 s8 t5b= y3 ni y3k3y3k3. Zpccrc won ni d72d72, f7of7o, w22, rokoso, f2nf2, gbangba, kqnm9kqnm9, jz6jz6 abbl

   

  T9bi jcun d72

  B9l5 n r8n kqnm9kqnm9.

   

  N7n5 zp9lz8se ni =r=zp-nl3 ti mqq n jcy[ n7n6 gb9l9h6n. +r=Zp.nl3 mqq n p-n =r=8se n7n6 gb9l9h6n ni bakan nqz ni 9 mqq n se zfik5n 8tum= f5n =r=8se.

  Tqd3 d8de f66.

  Igi nqz ga f7of7o.

   

  Iruf1/Orisii +r=Zp-nl3.

 8. Zw[n =r=zp-nl3 z8s2dq.
 9. Zw[n =r=zp-nl3 as2dq.

   

  +r=Zp-nl3 Z8s2dq: ni =r=zp-nl3 ti a k0 s2dq, ir5 =r= y87 k8 7 ni ju s7l3b6 kan tzb7 m3j8 l[. Zpccrc w[n ni: f7o, k7q, ganan l-gqn.

   

  ( l[ l-gqn

  Il3 nqz ga f7o

   

 10. +r=Zp-nl3 Aseda:. ni =r=zp-nl3 ti a s2dq lqti ara =r=zp-nl3z8is2dq n7pa s7se zp4t5np4 =r=zp-nl3 p-nb3l3

   

   K7q + K7q =  K7qk7q

   Wzd6 + Wzd6  =  wzd6wzd6

   P2l1 + p2l1 =  p2l1p2l1

   Jan + jan =  Janjan

   K1l1 + k1l1 =  k1l1k1l1

   

  Tobi n lzqg6n y=b=y=b=.

  Ad3 tcs2 m- 8r8n k7qk7q.

  As[ nqz ya p1rcp2rc.

  {b2 nqz ti tqn yqnyqn

  )s6pq m-l2 rokoso.

   

  IGBELEWON

  K[ orisii =r=zp-nl3 marunun s7l2 k7 o s8 l0 w-n n7 v9l9h6n.

   

  IWE AKAILEWA

  Adewoyin S.Y (2006) Imo, 4d4, Zxz zti Litireso Ile Eko Sekondiri Agba. Copromutt Publishers oju iwe 163.167.

   

   

  +R+&SE

   

 • Oriki
 • Iwulo =r=.8se
 • S7n5 ti a le gba lzti da =r=.8se mo.
 • Isori =r=8se.

  AKOONU : .

  =r=8se ni =r= t7 9 bq le d5r9 bii k9k9 f-nrqn n7n6 gb9l9h6n. +r=8se ni =r= t7 9 n t-ka s7 ohun t7 ol6wz se n7n6 gb9l9h6n. Lq8s7 =r=8se n7n6 gb9l9h6n k0 le n7 8tum= n7tor7 ohun ni 9 j1 0p9m5l3r9 f5n gb9l9h6n. Zpccrc: f0, f=, s[, rz, k[, w2, w7, g6n, s6n, tz, jc, lq, p4, jz, ti, j= abbl.

   Bzbq ra bztz.

   Ol5 f[ ax[.

  B7 a bq y[ =r=8se k5r0 n7n5 zw[n gb9l9h6n w=nyii k0 le ni 8tum=.

   

   +NZ T& A FI L$ DQ +R+.*SE M+.

  1  +r=8se ni 9 mqq n jcy[‘ l1y8n ol6wz. Ap ‘mo jc 2bz.’ ‘w-n gba ow9′.

  2  +r= t7 9 bq le t2l3 2r5n =r=8se ‘n’ gb[d= jc =r=8se. ap ‘Ad3 n k[ 8w3′ ‘ mzmq n se [b2.’

  3  +r= t7 9 bq jcy[ l1y8n ‘y90, mqa, fi zti ti gb[d= j1 =r=8se. Ap ‘Ak1k=- y90 se 8dqnw9′ ‘ol6k- mqa wq.’ ‘bzbq ti d3‘.

  4  +r= t7 9 bq t2l3 at-ka 8y7s9d8 ‘/0 gb-d= j1 =r=8se. Ap ‘ Bqy= k0 ra ax[.’ ‘ ol6k- k0 jc 2bz’.

   

  *S+R& +R+*SE.

   Or7s87r7s87 8s=r7 ni zw[n onimo g7rqmz p7n =r=8se s7 n7n5 4d4 Yor6bq.

 1. +r=*se Z8gbzb=: . ni =r=8se ti a mqq n lo zb= p2l5 r2 n7n5 4d4 Yor6bq. Ap ‘Tol5 s6n’ T-p1 k5r5.’ ‘ 0j0 r=’.
 2. +r=*se
  Agbzb=: zw[n +r= yii mqq n gba =r= or5k[ ni ip0 zb=. Zpccrc: Ad3 jc 2wz. K5nl3 gun igi, B-lq mu omi, Akck=- k[ 8w3.

   

 3. +r=*se As4b33r4 : . m3j8 nqz ni 9 wz n7n5 4d4 Yor6bq, zw[n nqz ni ndz/da zti nk-. F5n zpccrc ‘ mama da?’ ‘Bisi nk-?’.

   

 4. +r=*se Ax[k6nfq : . 4y7 ni +r= –ise t7 9 mqq n se ok6nfz 8s2l2, zw[n =r=8se ax[k6nfz ni; s[, mu, se, ko, fi, da. Zpccrc B-lq dq 2r7n pa m7. Bqd3 fi 8yz jc X[lq. O se ik5 pa ajq r2.

   

 5. +r=*se Cl1lz: . 4y7 ni =r=8se ti a le fi +r=or5k[ b= lqzrin n7n6 gb9l9h6n. Zpccrc bqw7, r1jc, padz, dzn6.

  Mama bq [m[ w7
  (baw7).

  B-lq r1 mi jc (r1jc).

  Bzbq da ixu n6
  (dzn6).

   

 6. +r=*se Zkznm9r5k[ : . 4y7 ni a s2dq lzti ara zpap= =r=8se zti +r=or5k[. Zpccrc T-p1 mut7 y9 [mu ‘+r= or5k[‘ oti ‘=r= 8se’].

  Mmama gunyan je ‘gun ‘=r= 8se’ iyan ‘+r= or5k[‘].

  Ab7-lq law- p5p= ”la ‘=r= 8se’ owo ‘+r= or5k[‘].

   

 7. +r=*se Aszp3j5we : . ni =r=8se t7 a mqq n l0 lzti s[ 8r7s7 nnkan. Zpccrc ‘B7s7 pupa f00’ ‘Ey7n Tol5 f5nf5n’ ‘ T-p1 ga’.

   

 8. +r=*se As[l6wzdzb= : . ni =r=8se ti ol6wz zti zb= le gbzp= ara w[n. 4y7 ni pe a l4 si ol6wz zti zb= ni ip0 padz lqzs7 8yzt= n7n5 v9l9h6n nqz. Zpccrc.

  )j9 n se w4r4 W4r4 n se )j9.

  Mo ti oj5 Oj5 t8 mi

  Mo jqyz Zyz mi jq.

   

 9. +r=*se Alapepada: . ni =r=8se ti a mqq n se zp4t5np4 f5n n7n5 v9l9h6n. Zpccrc *w[ ni 9 k6 mi k6.

  C r0 wq ro ire.

  Ay k0 f1ni f-r=.

  Ma da mi dq wzhqlz’.

   

 10. +r=*se Zs7np= : . ni =r=8se t7 9 mqq n j1 m3j8 tzb7 mcta n7n5 v9l9h6n p2l5 ol6wz kan. Iye =r= 8se ti o wa n7n5 v9l9h6n yii ni iye v9l9h6n ti a le ri fzy[. F5n zpccrc,

  {lq sun ixu tz  =  {lq sun ixu – {lq ta ixu.

  T-p1 ji cran jc  =  T-p1 jc cran – T-p1 j7 cran.

   

  IGBELEWON:

  Fa 8lz s7 8d7 =r= 8se n7n5 zr0k[ y87:

  On7r5ur5 kzy34f8 ni 9 k5n il3 ay3. Ol9w9 zti tql7kz l[ s6z. {l-gb-n 0un 0m6g= l[ bi r1rc. Ibi 8gb7n ti n sunk5n z8l9r7 ni zjznzk5 ti n pariwo or7 t7t9bi. Cni in5 n run n jow5 cni or7 n f-. Il3 ay3 y87 nqz ni K-l3dow9 ti bi [m[ m1j[ t7 Oy7b9y7 fi w[n dqj[, t7 8yq ol9w9 y[y[ wq di zgzn =sqn-an-gan.

   

  IWE AKZTILWA

  Adewoyin S.Y (2006) Imo, 4d4, Zxz zti Litireso Ile Eko Sekondiri Agba. Copromutt Publishers oju iwe 155.160.

  +R+ ZSOP+

 • Oriki.
 • Orisii w5nren +r=Zsop=.
 • Is1 ise n7n5 v9l9h6n.

   

  AKOONU

  +r=Zsop= ni zw[n w5nr2n t7 a n l0 lzti so zw[n =r= tzb7 v9l9h6n bi m3j8 tzb7 j6 b12 l[ p= di v9l9h6n kan. Zpccrc: Zpccrc =r= zsop= ni zti, afi, s6v-n, zm-, zyzfi, p2l5,zb7 abbl.

  Ad3 f1rzn 8rcs8  +  Tomi f1rzn 8rcs8   =  Ad3 zti Tomi f1rzn 8rcs8

  Il3 r2 t9bi +   *yzrq r2 k3r3   =  Il3 r2 t9bi s6v-n 8yzrq r2 k3r3.

  Zw[n zpccrc m87rzn ni: 0un, zfi, n7gbz t7, zb7, b12 ni, yqlz, tzb7 anb=s8 b-s7 abbl

   

  Ix1 t7 w-n n se n7n5 Gb9l9h6n: ise +r= ax[po ni siso =r= tqb7 v9l9h6n pap=.

  1.  ‘zti, p2l5, zti 0un’ ni a fi n so

   A.  +r=or5k[, m3j8 p= n7n5 v9l9h6n.

  zpccrc:

  Tol5 zti Oy4 l[ s7 8l5 [ba.

  T5nd3 p2l5 T9y8n l[ s7 *k0r0d5.

  {lq 0un Bqy= j[ n kzw3.

   

   B.  A le fi so =r= ar-p0 zfarajor5k[ m3j8 p= n7n5 8s[

  Apccrc

  *w[ zti 0un ni ol-r=

  Zw[n p2l5 4y7n k8 7 se cgb1

   

   D.  A le fi ‘zti, p2l5’ so =r= or5k[ zti =r= ar-p0 zfarajor5k[ p=

   

  zpccrc:

  *w[ zti Deinde ni mo r7.

  $mi p2l5 R9t8m7 n ka 8w3 8r0y8n.

   

  E.  S6v-n, tzb7, zm-. Z n lo zw[n [r= w=nyi lzti so v9l9h6n m3j8 p= ti zbqy[r7 r2 y90 j1 v9l9h6n [l-p= =r= 8se alqkznp=.

   

  Zpccrc:

   B-lq p4 m7 s6v-n n k0 dqh6n.

  Mzmq ni ow9 zm- w[n 0 ra ax[.

   

  IWE AKAILEWA

  Adewoyin S.Y (2006) Imo, 4d4, Zxz zti Litireso Ile Eko Sekondiri Agba. Copromutt Publishers oju iwe 1169.172.

   

  +R+ AT_K^N

   

  W5nr2n =r= at-k6n

  Ise ti won n se n7n5 v9l9h6n

  Ibi t7 w-n ti n jcy[

   

  AKOONU

  +r= – at-k6n ni =r= t7 z n l0 lzti s[ iha ti =r=.or5k[ m3j8 k[ si ara w[n. Zw[n w5nr2n at-k6n in5 4d4 Yor6bq ni: si, ti, ni. +r= at-k6n mqq n jcy[ sqqj5 =r= or5k[ n7n5 v9l9h6n. Zpccrc:  

  Ad3 ti /*kcjz l[ s7 )y8ngb0 ni znq

  Is1 ti +r= At-k6n mqq n se. N7n5 ihun v9l9h6n, =r= at-k6n mqq n t-ka:

  I  Ibi ti 4n8yzn tabi nnkan n lo. +r= atoka r2 ni – si

   

  Zpccrc:

   

  Mo l[ s7 *bzdzn.

  Od6duwz t2d9 s7 Il3 If2.

   

  II  O mqq n fi ibi t7 44yzn tzb7 nnkan t7 n b= hzn. ‘ti’ ni w5nr2n r2

   

  Zpccrc:

   

  D3l3 ti Zk5r1 d3 lqnzq

  Eru ti ori aja ja lule

   

  III.  +r= at-k6n mqq n se zfihzn ibi t7 44yzn tzb7 nnkan wz. ‘ni’ ni at-ka r2.

   

  Zpccrc:

  Tzlzb7 wz n7 *kcjz

  Ol5 wz n7 $k9

  Mzmq wz n7 il2 Ha5sq.

   

   

  IWE AKAILEWA

  Adewoyin S.Y (2006) Imo, 4d4, Zxz zti Litireso Ile Eko Sekondiri Agba. Copromutt Publishers oju iwe 168

   

   

   

   

  +R+ ZP#J%WE

  +r=.Zp3j5we.; ni +r= t7 9 mqq n yqn +r= or5k[ n7n5 v9l9h6n. Z n lo +r= zp3j5we lzti se zlzy3 y3k3y3k3 0hun ti z n s=r= ba n7n5 8s[. Zpccrc:

  {m[ pupa ni B6nmi.

  Cxin f5nf5n ni bzbq rz.

  {t7 l7le k0 dqra.

  *wz rere ni 2s- 4n8yzn.

  *r9 k-ns9nqnt8 l9 mqq n b2r2 =r= zp3j5we.

  Ap  

  +m[ k3ker3 ni mo j1.

  Inu zp9lz or5k[ ni =r= –zp3j5we mqq n wz.

  Ap

  *r8n r4d4r4d4 k0 yc [m[l5zb7.

   

   

  ORISII +R+ ZP#J%WE

 1. +r= Zp3j5we *p8l2. 4y7 ni zw[n =r= bii rere, k3ker3, nlq.

  +r= Zp3j5we 8s2dq.; 4y7 ni zw[n wunren =r=.zp3j5we ti a s2dq n7pa s7se zp4t5np4 cl1bc. Zpccrc:

  Mu .mimu

  ro .riro

  bo .bibo.

   

  2  +r= Zp3j5we t7 a s2dq n7pa zp4t5np4. Zpccrc:

  nla. ile nlanla ni won f5n wa.

   

  IGBELEWON

  T-ka s7 =r= zp3j5we ti 9 wz n7n5 v9l9h6n y87

 2. S7l4 m1fzm1fz ni ol6k- f5n wa.
 3. {m[ g7ga ni B-lq.
 4. Or5k[ rere szn ju w5rz 0un fzdqkz l[.

   

  IWE AKZTILEWA

  Adewoyin S.Y (2006) Imo,4d4, Zxz zti Litireso Ile Eko Sekondiri Agba. Copromutt Publishers oju iwe 152.154.

   

   

  ORISII ONA TI A N GBA SOGE NILE YORUBA

  ARA FINFIN

  EYIN PIPA

  TIROO LILE

  LAALI

   

  Oge sise ni a n pe ni oso. Oso ara, oso ile. Ki a se itoju ara, aso, ile ni gbogbo e dale lori. Ki a se itoju irun: irun didi, irun gige, iwe wiwe, enu fifo, ara pipa/jija eekanna gige ati bee bee lo ni a n pe ni imototo. Apeere oge sise nile Yoruba ni aye atijo ni ara finfin, eyin pipa, tiroo lile, laali, irun didi, enu fifo, ara pipa/jija ati bee bee lo. Eni ti o n maa n se itoju ara re ni a n pe ni afinju nigba ti a n pe eni ti ki i se itoju ara re ni obun.

   

  Ara finfin: Ara finfin je okan lara oge sise ile Yoruba.Oloola (awon to maa n ko ila fun eeyan ) ni o maa n se ara finfin fun eeyan. Won le ya orisiirisii batani si ara eniyan bi alangba, Ooya idirun tabi akekee. Gbogbo nnkan won yii ni won n lo lati bu kun ewa ara won.

   

  Eyin Pipa: Eyin pipa ni asa ki a da iho tabi alafo si aarin eyin meji to wa laarin gbungbun enu. Awon Yoruba gba pe eni ti o ba ni eji maa n ni ewa. Awon oloola ni o maa n se eyi pelu.

   

  Tiroo: Awon obinrin ni ni o maa n le tiroo ju. Won yoo maa fi igi iye ediye le si oju. O maa n wulo fun oju pipon ati eyikeyi arun oju. Awon iya olomo naa maa n lo o fun omode, ero won ni wi pe o maa n mu idoti kuro loju.

   

  Laali: Awon obinrin maa n le laali si atelewo ati egbeegbe ese won mejeeji. Bi o ba gbe tan won yoo ko ewe laali yii kuro ni oju ibi ti won ti koo kuro yi maa n dudu lati bu kun ewa won. Iru eyi maa n wopo ni Igbomina/Ilorin ati eya Hausa.

   

  IGBELEWON:

 5. Kin ni oge sise?
 6. Ko ona merin ti a n gba soge laye atijo.

   

  IWE AKATILEWA:

  1  Eko ede Yoruba titun (SSS) iwe kin-in-Eko ede ati asa Yoruba iwe kin-in-ni (JSS 1) oju iwe 90 – 93 lati owo egbe akomolede ati asa Yoruba.

  2  Eko ede Yoruba titun iwe kin-in-ni (J S S1 ) oju iwe 153-158 lati owo Oyebamji Mustapha.

   

   

  APAPO IGBELEWON

 7. Fa 8lz s7 8d7 =r= 8se n7n5 zr0k[ y87:

  On7r5ur5 kzy34f8 ni 9 k5n il3 ay3. Ol9w9 zti tql7kz l[ s6z. {l-gb-n 0un 0m6g= l[ bi r1rc. Ibi 8gb7n ti n sunk5n z8l9r7 ni zjznzk5 ti n pariwo or7 t7t9bi. Cni in5 n run n jow5 cni or7 n f-. Il3 ay3 y87 nqz ni K-l3dow9 ti bi [m[ m1j[ t7 Oy7b9y7 fi w[n dqj[, t7 8yq ol9w9 y[y[ wq di zgzn =sqn-an-gan.

 8. Salaye lori oge sise abinibi ile Yoruba.

   

  ATUNYEWO EKO

 9. Salaye lori aseyinwaye.
 10. Salaye lori asa eewo nile Yoruba.
 11. Salaye lori eto abinibi nie Yoruba.

   

  ISE ASETILEWA

 12. _____ ni opomulero fun gbolohun (a) oro-oruko (b) oro-ise (d) eyan
 13. E rowa ro ire je apeere oro-ise _____ (a) asoluwadabo (b) alapepada (d) agbabo
 14. Sola da obe nu. Oro_ise iru gbolohun yi ni (a) da (b) obe (d) danu.
 15. Awon wo lo maa n lo laali ju? (a) obinrin (b) okunrin (d) omode (e) arugbo
 16. Idi ti won fi maa n korin nibi ikomojade ati igbeyawo ni _________ (a) ounje jije (b) nitori ilu lilu ti o wa nibe (d) nitori a ki i saba korin lojoojumo (e) inu didun

   

  APA KEJI

 17. Salaye iyato meta laarin oro aropo oruko ati oro aropo aafarajoruko.
 18. Salaye iyato marun-un laarin oro oruko ati oro aropo oruko.
 19. Ko orisii ila marun-un ti awon Yoruba n ko.

   

  OSE KEFA

  ETO IGBEYAWO ABINIBI

  AKOONU

 • IFOJUSODE
 • ALARINA
 • IJOHEN/ISIHUN
 • ITOORO
 • IDANA

  ASA IGBEYAWO ATIJO (IBILE)

  IGBESE IGBEYAWO ALAYE

  Ifojusode Awon obi okunrin yoo maa fi oju sile wa obinrin.

  Iwadii Won yoo se iwadii idile obinrin naa ni aarin ilu. Won yoo tun se,

  iwadi lowo ifa.

  Alarina Alarina ni won yoo maa ran si ara won (oko ati Iyawo afesona), Boko ba

  moju aya tan, alarina a yeba.

  Isihun/ijohen  Gbigba ti obinrin gba lati fe okunrin.

  Itoro Awon ebi okunrin yoo wa toro omobinrin ni owo obi re.

  Baba gbo, iya  Awon ebi mejeeji gbo, won si gba pe ki obinrin ati okunrin fera

  gbo

  Idana Ebi oko yoo gbe eru idana lo fun ebi omobinrin ti ojo igbeyawo won

  ba ku feere. Isu ogoji, orogbo ogoji, obi ogoji.

  Ifa iyawo Baba iyawo yoo difa ni aaro ojo igbeyawo lati mo ile oko naa yoo se

  ri boya yoo san sowo somo.

  Ojo igbeyawo  Ale ni awon ebi ati ore iyawo yoo ba a palemo, won yoo sin iyawo lo

  si ile oko pelu orin ati ijo titi yoo fi de enu ona oko re.

  Ese iyawo Ni enu ona abawole won yoo fi omi we ese iyawo naa.

  wiwe

   

  Ibale  Ti iyawo ko ba ti i mo okunrin kan ri, ti oko re ba a nile, oko yoo gbe

   ekun agbe emu tabi ile isana kikun ranse si obi iyawo pelu owo ibale.  

   

  IGBELEWON

  1.  Ki ni a n pe ni ifojusode ninu eto igbeyawo abinibi

  2.  Se alaye ise alarena

  3.  Kini ijohen tabi isihun tumo si?

  4.  Kini iyato laarin itoro ati idana?

   

  IGBEYAWO ODE ONI DEETI……………………

   

  AKORI ISE:

  AKOONU:-

 • IGBEYAWO SOOSI
 • IGBEYAWO MOSOLASI
 • IGBEYAWO KOOTU

  Lode oni, aye ti di amulumala. Orisirisii ona ni a n gba gbe iyawo. A n gbe iyawo ni ile Olorun, a n gbe e ni kootu, a si n gbe ni mosalasi. Igbeyawo soosi yii fese mule laarin awon onigbagbo, igbeyawo mosalasi si mule laarin awon musulumi.

   

  Igbeyawo soosi ni eyi to maa n waye laarin awon elesin Kristeni ninu ile ijosin won, sugbon ki eto igbeyawo yii to waye ni won yoo ti maa kede eni to ba ri idi ti won ko le fi so oko ati iyawo naa papo ko tete wa so bi bee ko, ki eni be gbe enu re dake laelae. Bi won ko ba tiri enikeni ko yoju ni won to le so awon mejeeji po. Iru igbeyawo yii ko faye gba ju iyawo kan lo.

   

  Igbeyawo mosolasi maa n waye laarin awon musulumi, eyi faye gba ju iyawo kan lo nitori won ni “me” ni Olorun wi, ti agbara eniyan ba ti kaa. Awon musulumi a maa fi omo se saara lai je pe onitohuni fi okan sii tele eyi ni pe ki won fun eniyan ni iyawo lairo tele (ki won fun eeyan ni iyawo ofe). Eyi ni won naa n pe ni iyawo saara.

   

  Orisii igbeyawo yii fese mule daadaa nile Yoruba nitori esin igbagbo ati Isilamu to fese mule lode oni. Gbogbo ilana lati ibi itoro titi de idana maa n saba je eyi ti a n tele.

   

  Awon loko laya miiran a ma n se igbeyawo alarede ti o je pe won a lo si olu ile-ise ijoba ibile tabi Kootu lati fowo si iwe ase lodo ijoba, won a si fi bee gba oruka arede. Eleyii naa ko faye gba ju iyawo kan ati oko kan lo.Igbeyawo kootu ni a n pe e.

   

  Ni aye ode oni ko si ohun to n je ekun iyawo mo, opolopo awon wundia iwoyi ni won ti daju, gbogbo won ni oju n kan lati lo ile oko. Ko tile sohun to fe pawon

  lekun nitori won ko ka ile oko si ohun babara.

   

  APAPO IGBELEWON

 1. Salaye lori igbeyawo aye ode oni
 2. Ko iyato meta laarin igbeyawo aye ode oni ati aye atijo.
 3. Salaye lori ise ode

   

  ISE ASETILEWA

  1.  Awon………….. lo n se igbeyawo soosi (a) Musulumi (b) Igbagbo (d) Aborisa.

  2.  Awon …………………………lo n se igbeyawo Mosolasi (a) musulumi (b) Igbagbo (d) Aborisa.

  3.  Awon ……………………………lo maa fi omo se saara (a) Onigbagbo (b) Alarede (d) Musulumi  

  4. Awon to maa n fe iyawo ju eyo kan lo lode oni ni (a) musulumi (b) soosi (d) kootu

  5.  ‘titi iku yoo fi ya won’ inu inu irufe igbeyawo aye ode oni wo ni eyi je mo?. (a) musulumi (b) soosi (d) kootu.

   

  APA KEJI

  1.  Kini a n pe ni idana ninu eto igbeyawo nile Yoruba

  2.  Kini ijohen, lati odo tani ijohen ti n wa?
Share this:


EcoleBooks | 2ND TERM SS3 YORUBA SCHEME OF WORK AND NOTE

subscriber

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Accept Our Privacy Terms.*